Smiley face

Ebola Ti So Ilu Liberia Di Ile Iku

Oku awon eniyan ti Ebola da loro si n po sii loju popo pelu bi awon ebi won se ko won sile ni ilu Liberia.

Bi o tile je wi pe Aare ilu naa, Arabirin Ellen Johnson Sirleaf so fun awon oniroyin wi pe awon gbiyanju lati dena itankale arun naa, sibesibe eyi ko dawo iye awon eniyan ti oku won rare loju titi bi oku oja duro.

Eniyan le se agbako arun Ebola nipa fifi owo kan alaisan to ni arun naa lara, ibalopo, ito enu, imi, ito ati oogun (sweat).

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment