Smiley face

Se Awada Ni Abi Otito: Irawo Alawada Kerikeri Fe Di Gomina?

Julius Agwu la gbo wi pe o n gbiyanju lati gbe apoti idibo lati di gomina Ipinle Rivers. Olayemi Oniroyin ko ti ri aridaju igbese naa, se e mo wi pe awada awon alawada po. O le je awada, o si le je otito. Bo ba se je, e tun maa  gbo.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment