Smiley face

Iberu Ebola Ni Ipilese Ogbon: Awon Banki Gbe Ara Mii Yo

Awon osise banki kan ni ilu Eko ti bere si ni fi nnkan bo owo won bayii latari iberu arun buruku Ebola.

Glove ti won ti bowo yii ni won lero wi pe yoo gba won lowo ipalara Ebola nigba ti awon ba n da kositoma to ba ni arun naa lara lohun eleyii ti ko ti je jade.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment