Iya to bi gomina Ipinle Oyo nigba kan ri, Senator Rasheed Adewolu Ladoja, Alhaja Alimotu
Shadiya Atoke Ladoja ti je Olorun nipe ni ale ana (27-8-14) ni nnkan bi ago meje ninu ile omo re to wa ni Bodija.
Omo odun merinlelaadorun (94) ni mama ki iku to ja pati mo awon omo re lowo.
Ki Oluwa ba te mama si afefe rere. Amin.
0 comments:
Post a Comment