Ninu iroyin tuntun: awon omo ologun ilu Cameroon ti fi emi awon omo Boko Haram ti won ko din ni metadinlogbon (27) sofo lojo Isegun (26-8-14) to koja yii lenu bode ile Nigeria ati Cameroon.
Awon omo Boko Haram ti won pa yii ni won n wa ibi ti won yoo fori pamo si leyin ti won se ise ibi won tan ni agbegbe ila-oorun Nigeria.
['Olayemi Oniroyin, se awon to pa Boko Haram naa ni yii ninu aworan oke yii?'... Rara o! Uncle Jona ni awon eleyii fe wa ri nipa awon omobirin to sonu ni Chibok. ...'Mmmmmh...']
0 comments:
Post a Comment