Smiley face

'Odale Gbaa Ni Oyinlola' - Omisore

Senator Iyiola Omisore ti n dije fun ipo gomina ni Ipinle Osun labe asia egbe PDP ti fesun kan gomina Ipinle naa nigba kan ri, Omo'ba Olagunsoye Oyinlola gege bi odale lasanlasan pelu bo se kuro ninu PDP bo sinu APC.

"The former Governor is a confirmed serial
betrayer, a politician who had lost whatever little followers he had due to his inconsistency, political somersaults and unreliability in political alliances."

Omisore tun fi kun un wi pe igbese Oyinlola ko ni ohunkohun se pelu boya wi pe oun yoo bori ninu idibo ojo Satide, ojo kesan-an osu yii abi beeko.

O ni opolopo awon omo leyin Oyinlola si wa pelu Omisore eyi to je ki okan oun bale wi pe didun ni osan yoo so fun egbe alaburada.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment