Smiley face

Idi Omoge Onibadi Olokiki Ilu Amerika Ranju Bi Eja Sabalo


Sebi ohun gbogbo ti Kim Kardashian ba se pata ni awon oniroyin amuludun agbaye n so di iroyin leti omo araye.
Nibayi, won ti foju kan omobirin, eni odun metalelogbon ni papako ofurufu L.A nibi to ti n mura lati fo pelu omo re.
Inu sokoto onikaki ni omobirin naa kosi, pelu ibadi re ti fi n pawo se ranju kankan bi oju eja sabalo ti won je ni ilu Ilorin.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment