Smiley face

Apa Kan Ewure, Apa Kan Aguntan

Orisii eranko tuntun kan ti wa saye eleyii ti apakan re je ewure ti apakeji re si je aguntan.

Eranko tuntun yii, eleyii ti oruko re n je Butterfly ni won ni baba re je ewure nigba ti iya to loyun re sinu je aguntan.

Oju ati ese naa lo fi jo baba re nigba ti awon ara yoku si ba iya re lo.

Awon onise iwadi kan ni won da awon orisii eranko meji yii papo, abaje ise akanse won si ti di okiki kaakiri ero ayelukara nigbogbo agbaye.

Igba wo ni yoo da agbamurere ati kinihun papo?

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment