Olusola Allyson ti si ofiisi re tuntun si ilu Eko eleyii ti o je ko rorun fun awon onibara re lati ba dowopo ju ti ateyin wa lo.
Adiresi soobu naa ni yii; D195, Ikota Shopping Complex, VGC Lekki, Lagos.
Ofiisi naa rewa pupo eleyii to je idunnu nla fun omobirin olorin naa.
Adura wa ni wi pe won yoo ma rise o.









0 comments:
Post a Comment