Ta ba n paro fun ra wa lo ku. Aye oloba, ajeku ni. Alaafin Oyo si ti kuro loba lasan, Oba Lamidi Olayiwola Adeyemi ti doosa akunlebo. Owo, agbara, ipo ati okiki si ti so igbe aye re di India fiimu eleyii ti enikeni ko le e wo tan rara.
Olayemi Oniroyin ki lo ri?
Gomina Ipinle Bauchi, Isa Yuguda lo ranse pe kabiesi wi pe ko wa ki awon jo se Doro-Faaji.
Odindi baalu jeeti ni omo Atanda gbe lo pelu awon iyawo re.
Talo so wi pe aye oloba ko dun na?
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment