Smiley face

Iya Agbalagba Be Sinu Odo Iku Ni Thiland

Obirin eni odun marunlelogota (65) lo ti seku pa ara re ni ilu
Bangkok, Thailand pelu bo se funra re ko sinu odo ooni(crocodile) to
wa ni Samut Prakarn Crocodile Farm &
Zoo.

Wanpen Inyai to seku pa ara re yii ni won ni o seese ko je wi pe o ti
wa ninu ibanuje kan ti ko wi fun enikeni ko to seku pa ara re.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment