Won ti bere Ipolongo e-dibo-fun-Aare Goodluck Jonathan ni Ipinle Rivers. Ipolongo yii lo bere ni Pota to je olu ilu ipinle naa ni papa isere Liberty nibi ti awon olorin ko ti korin kankan yato si Goodluck Jonathan lawa n fe lodun 2015.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment