Eda o laropin. Ati wi pe ko si eni ti iyanu ko le sele si lojiji. Niwon ti o ti je wi pe awon olomoge olorin onidi nla bi Nicki Minaj ti ilu Amerika ni won pawo (bi orin ni won fi n pawo bi idi ni mi o tile mo sugbon won pawo).
Nibayii, Miley Cyrus ti oun naa je olorin ti lo fon idi re lodo awon foganaisa eleyii to so ukwu re di apoti aje ojiji, e si le pe idi re ni magasuku uchena, seemu naa ni. E si tun le pe ni apata paara oke kabiti; sebi omi. eko, eko naa ni.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment