Smiley face

Davido Wu Iwa Omo Olorun Si Wizkid

Bibeli mimo ti mo maa n ka lojoojumo fi ye mi wi pe alabukun fun ni olulaja, omo Olorun ni a si maa pe e. Pelu awuyewuye ikunsinu to ti n waye laarin Ayo Balogun (wizkid) ati Dafiidi Adeleke (Davido) dabi eni wi pe o ti n wa sopin pelu bi Dafiidi se gbe igbese omo Olorun nipa kiki Wizkid ku ori ire awo re tuntun to pe akole re ni "AYO" to gbe jade.

Igba melo la fe lo laye ti a maa wo ewu irin? Bakan naa ni oju orun teye e fo laiye kolura won.

Olayemi ni oruko mi. Ire ni maa ma se mi o ni seka.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment