Smiley face

"Sebi O Mo Eni To Pa Mi": Oku N Ba Araaye Soro

Ojo kerinla osu keji odun 2013 ni Goldie ku. Gbogbo eniyan lo si mo Derenle ati Goldie gege bi ore timotimo. Iku Goldie dun ore re gidigidi eleyii ti ko le pamora pelu bi omije se maa n jade loju re ni gbogbo igba ti won ba daruko Goldie.

Sugbon ohun to yanilenu ni oro ti Derenle so pelu awon oniroyin nikopekope yii:

" I kept seeing her in my dreams and
she keeps telling me you know who
killed me and you are not doing
anything about it. I'm not kidding.

You know these things, we actually don't believe in (the) supernatural. I have a friend who can bear me witness to that. And then I have to call my mum who prayed.' Oro enu Derenle.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment