Sebi okan soso ni Olorun ijo mimo, ko baa je Nigeria tabi Amerika, okan soso ni emi mimo Oluwa oga ogo.
Aimoye awon eniyan ti bere si ni yin Olorun ijo mimo ni ilu Amerika pelu awon orin emi nla eleyii to n ja ide sonu to n ti enu Atorise jade.
Atorise se alaye awon orin tuntun yii gege bi imisi lati oke orun wa. Omokunrin yii si n tesiwaju ninu ise Oluwa ni ilu Amerika.



0 comments:
Post a Comment