Lara awon omo ole omo yibo ti won maa n se ayederu fiimu agbelewo ti kosowo Kunle omo Afolayan nigba ti won n gbiyanju lati ta ayederu Half Of Yellow Sun fun-un nigboro.
Oserekunrin naa na won sare leyin igba to gba awon fiimu naa sile lowo won.
Bakan naa lo si ro awon ara ilu lati gbogun ti awon ti won se ayederu fiimu Nollywood.


0 comments:
Post a Comment