Okan lara awon aworan lati ibi isere tiata Nigeria ni yii. Nibi ti Ronke Oshodi Oke ti n ba Mr Saka sere leyin itage.
Ohun ti mo se akiyesi nipa awon alawada inu fiimu ni wi pe awada won nisise ko pin si ori itage nikan. Nigbogbo igba nibikibi, won kii ye pa awon eniyan lerin.
0 comments:
Post a Comment