Idije ere boolu ile adulawo AFCON 2015 eleyii ti ile Morocco to ye ko gba alejo ere boolu naa ti n bebe wi pe ki won sun ojo idije naa siwaju latari erujeje Ebola lapa iwo-oorun Afirika.
Ajo ere idaraya ile Adulawo, CAF ko jale wi pe awon ko le sun siwaju, ati wi pe dandan ni ki idije naa waye losu kinni odun 2015.
Ileke ma jaale, ma ja ode. Sebi ibi kan ni ile yoo jasi. (Ko saa ma ti jasi 'nu pata Bose.lol).
Nibayii, ile Morocco ti jawo nigba ti Equitorial Guinea ni awon setan lati teri si igbalejo ere boolu naa.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment