Smiley face

Aisha Ti Ku ooo!

Eniyan to kan lo mo, Edumare ma je ka se konge aburu. Aisha ti lo sorun lonii nigba ti oko (car) koluu nigba to n lo si ile iwe lori okada ni ilu Abeokuta.

Edumare ba wa tu obi omobirin naa ninu. Bi eniyan ba je ori ahun, to ba de ibi ti moto ti run ori Aisha mo okada, onitoun yoo bu omi loju surusuru.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment