Smiley face

Ipadabo Abija: Abubakar Shekau Pada Si Chibok

Iroyin tuntun ti kan wa wi pe awon omo alakatakiti esin Islam taa mo si Boko Haram tun ti pada lo se abewo si Chibok nibi ti won ti ko aimoye awon omo obirin salo lojosi ni Ipinle Borno.

Ninu abewo won tuntun, aimoye awon eniyan ni won ran lo sorun ni agbegbe naa. Won si tun kede wi pe agbegbe naa ti wa labe akoso awon bayii gege bi Islamist caliphate.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment