Awon oro kan ti beere sini run kiri bi iso broda Jelili wi pe Gomina Ipinle Oyo nigba kan ri, Christopher Adebayo Alao-Akala ti fi egbe PDP sile bo sinu egbe APC.
Bi o tile je wi pe iroyin naa ko ti de gbangba, enikeni kosi ti ri aridaju titi di akoko ti iroyin yii fi jade.
Sugbon ohun kan to daju ni wi pe egbe PDP ko setan lati fun Aloa-Akala ni awon anfaani to n beere fun lati kopa ninu eto idibo odun 2015.
Ti oro naa ba lo jasi otito, nje osan egbe APC le sun didun fun Adebayo Alao-Akala baba Olamiju bi?
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment