Awon ero oko ofurufu bi mokandilogota (59) ati awon osise pelu awako ofurufu bi merin (4) ni ori ti koyo nibi ijamba oko ofurufu ti ko ba waye ni papako ofurufu ilu Ilorin nirole Satide [29-11-14] to koja yii nigba to n sare lo loju ona fifo ati biba awon baalu to wa ni papako ofurufu naa
Oko ofurufu ile ise Overland Airlines ti nomba re je 051175/1176 ni awon ero oko naa di ebi isele naa ru nipa aibikita ati idagunla.
Kosi eni to ba isele naa lo, kosi si eni to farapa rara.
A ni fi ojo olojo lo o. Amin
Home / Uncategories / Awon Eniyan Metalelogota (63) Lori Koyo Ninu Ijamba Oko Ofurufu Ni Ilu Ilorin Afonja
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment