Smiley face

Ajo NFF Ti Sangi Mo Stephen Keshi Lori: Ori Keshi Ko Si Nibe Mo

Ajo ti n ri si eto ere boolu-alafese-gba ti ile Nigeria, NFF ti da akoni-moogba ere boolu agba egbe Super Eagles, Ogbeni Stephen Keshi duro. Igbese tuntun yii lo waye lojo Abameta to koja yii leyin abajade igbimo teekoto ti won ni ki won se iwadii nipa ise iruju maanu naa eleyii ti won ni ko pegede lati tesiwaju gege bi akoni moogba fun egbe agbaboolu Naijeria.

Nibayii, won ti jawe gbele-e fun Stephen Okechukwu Keshi, eni ti n se enikeji ti o gba ifi eye Africa Cup of Nation gege bi agbaboolu ati akoni-moogba leyin Mahmoud El-Gohary ti ile Ijibiiti.

Nje igbese yii dara bi?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment