Smiley face

Eri Awon Eniyan To Ti Lo Alubosa Fun Iwosan Ara.

Laipe yii la gbe sori ikanni Olayemi Oniroyin nipa ise iwadii tuntun to n se alaye bi alubosa se n wo aisan iba ati awon kokoro ara mii. Ti eyin ko ba ri atejade naa ka, e le ka nipa sise ayewo linki yii : http://bit.ly/1JN8K2I

Sugbon ohun ti mo fe se afihan re labe koko iroyin yii ni eri awon eniyan ti won ti lo alubosa naa. Eleyii ti eyin naa le ka fun ra yin.

A maa reti awon eri ti yin naa laipe.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment