Smiley face

Bukola Saraki Wo Gau: Won Pada 'geti' Maanu Naa

Leyin awon esun bi metala ati esun iro funfun ti Bukola Saraki pa nipa jijewo dukia to ni. Ile ise ijoba apapo, eka ti awon onidajo ti pase ki ile ise olopaa ile yii, labe akoso ogbeni Solomon Arase lo gbe Saraki latari wi pe o ko lati yoju si ile ejo lori awon esun ti won fi kan-an.


Won ni maanu naa jo ra re lo ju pupo ju. Se tori wi pe o je aare ile igbimo asofin agba lo je ko maa se galigali, ko maa se bi eni wi pe oun ti ga jofin lo?

Bi o tile je wi pe Sariki ti pada toro aforijin, sibesibe onidaju Danladi Umar ni a fi ti awon olopaa ba gbe e, ki won di bi eru okirika, ki won si so jua sile niwaju oun.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment