Smiley face

Leta Si Dayo Amusa ati Fathia Balogun: E Ma Pada Sidi Aso Esubeleke Leyin Ti E Ba De Lati Ilu Mecca

Leyin afihan foto awon irawo oserebirin, Dayo Amusa ati Fathia Balogun, awon ololufee won ti bere si ni ki won ti won si n se adura wi pe ayo ni won yoo pada wa sile.

Nibi ti awon kan ti n ki won naa ni awon kan ti n "adifaisi" won wi pe, ko ba dara ti won ba le maa mura gege bi omoluabi gege bi won se mura ninu aworan won ni ilu Saudi Arabia.

Sogbon so posibu sa? Bi won tile fe maa mura bi musulumi ododo, se ise aje won le gba won laaye?

http://www.facebook.com/photo.php?fbid=891511200934764&set=gm.1054955661222409&type=1
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment