Smiley face

Dapo Lam Adesina n fo lo si ilu Jamani

Dapo Lam Adesina
Omo gomina ipinle Oyo nigba kan ri, to tun je okan lara awon omo ile igbimo asoju-sofin ilu Abuja, Dapo Lam Adesina ti n gbera lo si ilu Jamani bayii lati lo yanju awon akanse ise ilu ti won gbe le e lowo. 


Onarebu Dapo je okan lara awon oloselu ti won maa teti si edun okan ara ilu, ti won si n se ise ilu pelu ododo. O feran awon odo, bakan naa ni ki i fi awon eniyan re sere rara. 

Adura wa ni wi pe ki Oba oke ba wa solo-sobo ni alaafia. Amin
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment