Smiley face

Ohun ti Laide Bakare gbe soke ko daa rara

Laide Bakare ti pada si lo n se esesaisi lati pada ri bi omidan, se e mo wi pe awon obirin kii fe darugbo kiakian, ka to wa so wi pe osere. 


Bakan naa ni awon onise tiata kii fe e kuro nita boro. Gbogbo ona ni won si maa n gba lati gunrege loju awon onibara won.

Ju gbogbo, o se je ibaradi ni iya Simisoluwa gbesoke fun wa?  Eleyii ga ju!

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment