Smiley face

Aye awon asewo nile awon omo yahoo-yahoo

Bi yahoo-yahoo ni won ni abi ogun oloro ni won gbe, ta lo mo. Sugbon o daju wi pe, eni to n sise gege bi omoluabi ko ni da iru eleyii lasa wo laelae

Ori ayelujara ni aworan yii ti bere si ni fonkiri, eleyii to n se afihan awon asewo ti won jo mojumo, ti won si moti yo keri nile onibara won.

E wo bi awon omo ti baba ati iya bi se pate ara awon sile nihoho.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

2 comments:

  1. Opin aye ti Olorun wi lo tide yi ,ka sori ki adun aye ma gbe wa lo .

    ReplyDelete
  2. a strategic solution designed to enhance the performance of email marketing efforts. In this article, we'll explore the concept of email warmers, their significanceMail Warm

    ReplyDelete