Smiley face

Se eyin ti gbo nipa itan Morufa Eko?

Won mu Morufa wa lati ilu Ibadan wa si ilu Eko lati wa sise aje. Sugbon nigba to d'Eko, oko anti re to mu wa s'Eko ni won jo n ni ibalopo nikoro. Sugbon oko anti re gan-an ni asiri kan ninu okan re eleyii ti ko han si Morufa yato si ibalopo to waye laarin awon mejeeji.

Lati kan itan lati oke dele,

Morufa Eko ti pada si oju iworan yii. E le ka itan naa nisale---------















Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment