Smiley face

Ara oto lati owo Tunde Kelani

Agbaoje ninu ise fiimu, Tunde Kelani, ti setan  lati bo soju ise nipa fifi ojulowo imo ye awon eniyan ti won gbero lati di eni atata taye n fe nidi ise fiimu. Ojo kerindinlogun osu  karun-un odun yii ni ileewe naa yoo bere igbaniwole. E yera kan si won fun alaye kikun.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment