Smiley face

Omokunrin to yipada si obirin gbe oge tuntun yo

Orekelewa omidan SaHHara tun jade bi ojo nigba to se abewo si ile ise iroyin BBC ilu London, nibi won ti n fi oro wa lenu wo. Ninu iforowero to waye naa ni Omokunrin to yi iseda re pada si ti obirin ti n se awon alaye idojuko eleyii ti awon omo Naija gbe koo lojo saaju ko to fi ilu Naijiria sile lo si ilu UK.
Okunrin ni Miss SaHHara tele, subon bayii eniyan ko tile le mo pelu ebun nla ti n be ni igbaaya re.
 E tun le ka alaye lekunrere nipa Miss SaHHara NIBI
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment