Smiley face

Agbero fo kondokito monu gota n'Ikeja


O ti pe ti awon agbero ko ti gbadun paro awon Bus-Conductor. Idi ni wi pe, ti awon agbero ba ti beere owo lowo Kondo, agidi ni won fi n sanwo. N'Ikeja lana ni iru isele yii tun ti waye nigba ti Kondo yari wi pe, oun ko ni sanwo nibudoko to ti duro.


A se Kondo yen maa pada jeya, o n pariwo "gbera...gbera" fun dereba oko nigba ti agbero n beere owo lowo re. Kondo yen sebi Mayweather alagbara, a se o ma pada ba iya nibe loju paali ni.

Ojo-ese nibe naa ni agbero ti wo Kondo sile, to si bere si ni ko igbati bo o ni paari. Lati ibe lo, lo tun fi taari re sinu gota. To siro potopoto gota si Kondokito naa lenu.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment