Smiley face

Iku Ronke Shonde: Ibi aye foju si, ona o gbabẹ

Ibi won foju si, ona o gbabẹ lo. Won ti se ayewo oku Ronke Shonde ti won loko re lu pa leyin to kefin wi pe iyawo re n se asemase. Awon agbofinro ti gbe oku obirin naa lo si osibitu fun ayewo. Ayewo ti wa jade bayii. Ohun ti ayewo wi ni pe, ki i se nipa itaporogan, tipatikuuku tabi ijakadi ni obirin naa fi ku.

Eleyii si tako aheso wi pe, okunrin naa fun iyawo re lorun pa ni. Ju gbogbo re lo, iwadii si n tesiwaju lati mo iru iku to pa abileko to ku iku ojiji naa.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment