Smiley face

Agunbanirọ obirin fi idi ati ọyan rẹ se saara fọkunrin meji

Se agunbaniro si ni awon eleyii abi awon omo orita? O je ohun itiju gbaa lati ri awon obirin ki won ma fi ara won se eleya ni gbangba ode. Nigba ti omobirin ti won bi nile ire yodi si okunrin kan leyin to si tun ko oyan re mejeeji le ikeji lọwọ. Se ọlaju ni ka pe eleyii tabi ibẹrẹ were?

----------------------------------------------------------------------------------
Se ẹyin ti gbọ nipa Samuel Oyindamola olorin ti n fi ohun ogo gbe Olorun oga ogo ga? E le gbo orin naa NIBI
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment