Smiley face

Njẹ ojulowo orin igbagbọ gidi si wa laye ode oni?

Bola Aare: Okan ninu awon ojulowo olorin emi gidi
Ojulowo orin ẹmi ti n parun. Ti a ko ba kiyesi daada, ojulowo orin ẹmi gidi yoo wọle lọ raurau. Pupọ ninu awọn olorin kristẹni ni aye ti ja iransẹ orin ẹmi ti a fi le won lọwọ gba. Eyin onigbagbọ aye, ẹ maa fura! Ti Jesu ba pada de, njẹ yoo wa ba igbagbọ gidi bi? Olorun ọga ogo n wa awon olusin ti won yoo ma yin ninu ododo ati ninu emi. Njẹ iru awon orin wonyii, ti won yin Oluwa ninu ododo ati ẹmi si wa?  
Se e ranti Arabirin D.A Fasoyin, olori egbe Good Women?
Samuel Oyindamola, ọdọmọde olorin emi tuntun ti ẹmi mimọ n gba ẹnu rẹ kọrin ogo ti jade pẹlu awo orin rẹ tuntun to pe ni SEMI LOGO. Ninu awo orin tuntun naa ni mo ti tọrọ anfaani lati se afihan ọkan ninu awo orin naa to pe akọlẹ re ni ỌPẸLOYẸỌ.
Ajinyinrere Adelakun lo ko amọnatete maa bọ
Orin iyin lati inu emi ti n bu ọla ati ogo fun Asẹda, Adẹda, Olubori aye, Ọga ogo lori ite mimọ. E ma jẹ ki n gba koko yin ju. Ẹ Download orin naa ni kiakia.


Download

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment