Smiley face

Chinedu ti pa ọmọ rẹ nibi to ti n na iyawo rẹ

 gbẹni Chinedu lagbọ wi pe o bẹrẹ si ni na iyawo rẹ latari wi pe ko ba a fọ asọ rẹ. Ni akoko ti Chinedu na iyawo rẹ yii ni iyawo sare gbe ọmọ won, omo odun meta, boya nipa bẹẹ, ọkọ yoo dẹkun ati maa rọjọ ẹsẹ fun un.
Sugbon Chinedu ko wo tọmọ rẹ rara, bo se ni ki oun ju isẹ si iyawo rẹ, omo won odun meta lo fara gba isẹ gbigbona to n gbe bọ, ti omo naa si se bẹẹ koja sorun. Agbegbe Umuchima to wa niluu Owerri nipinle Imo ni isele buruku yii ti waye. Oju Chinedu ti ja bayii, ẹkun ni  sun bi egbere lati igba ti isele naa ti waye.





Njẹ ojulowo orin igbagbọ gidi si wa laye ode oni?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment