Smiley face

Olorun ti se ore ibẹta fun ẹni kan soso

Fi okan si i, fi igbagbọ si i, Olorun ko gbagbe rẹ. Bi ẹkun pe dalẹ, ayọ n bọ lowurọ. Olorun ko si gbagbe enikeni. Mo fi da ọ loju wi pe, Yaradu  yoo da ọ lohun ayọ laipẹ. Ko ni i se pelu iye odun ti o ti n woju Oluwa fun ohun ayo tabi ohun rere, Ire ti ẹ naa n bọ. Awon eniyan yoo si ki iwọ naa ku ori ire laipe. Ezenwa Esther Adaeze ti bi ibẹta bayii, ayọ meta fun enikan soso. 

Ohun to ko sori Facebook ni yii:


"Whr do I start 4rm tnkin d GOD of overdo,GOD of sings an wonders,GOD of miracle worker, hm! Am short of wrds,I never new he will honour me dis way, tnk u LORD 4 blessing Me wit a cute an lovely children at ones(2boys an a girl) jony dat would hav taken me 5 to 6 years d lord has decided to make it 9months.. I pray dat,dat God dat has decided 2 honour an 2 bless me wt 4 kids under 2 an half yrs of marriage wil do it 4 as many dat are in need of it IN Jesus NAME!!!"

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment