Smiley face

E wa wo Kehinde Obasanjo Aremu baba Iyabo


Foto baba olokada yii ti won ri niluu Asaba lo ti bere si ni fo kiri ori ayelujara bayii. Awon eniyan ni baba naa jo aare ana, Oloye Olusegun Aremu Okikiola Mathew Obasanjo baba Iyabo.

Se Kehinde Obasanjo ni, abi ka gba wi pe meji-meji ni Olorun da awon eniyan gege bi igbagbo awon Yoruba?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment