Smiley face

Kayeefi sele niluu India: ara eeyan n le mo irin bi magineeti

 

Arakunrin ti oruko re n je Arun Raikwar lati orileede India lo sadeede sakiyesi wi pe irin le mo oun lara bi igba ti magineeti ba gberin. Okunrin naa ti lo se ayewo lodo awon dokita, ko ma je wi pe adanwo kan ti de ba a laago ara. Sugbon ti won ko ri ewu kankan ninu ilera ra. Awon kan tun wi pe, ko ma lo je agbara airi kan ti wole si aago ara maanu naa eleyii ti ko fura.




Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment