Smiley face

E ku ojo isimi: Okunkun ko le bori imole


  1. Ni àtetekọse ni Ọ̀rọ wà, Ọ̀rọ si wà pẹlu Ọlọrun, Ọlọrun si ni Ọ̀rọ na.
  2. Oun naa ni o wà ni àtetekọṣe pẹlu Ọlọrun.
  3. Nipasẹ̀ rẹ̀ ni a ti da ohun gbogbo; lẹyin rẹ̀ a ko si da ohun kan ninu ohun ti a da.
  4. Ninu rẹ̀ ni ìye wà; ìye naa si ni imọlẹ̀ araye.
  5. Imọlẹ na si n mọlẹ ninu òkunkun; òkunkun naa kò si bori rẹ̀.


Iwe Johanu 1:1-5
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment