Smiley face

EFCC ti siwee iranti kan Omisore: Won ti gbe WANTED le e lori

Nibayii, ajo ti n gbogun ti iwa jegudujera,The Economic and Financial Crimes Commission (EFCC), ti gbe atejade kan jade lonii, May 24, eleyii ti won ni awon wa Senator Iyiola Omisore.

Igbakeji gomina ipinle Osun tele yii ni EFCC n wa latari N700M to bo sii lapo lati owo oludamoran funjoba nipa eto abo lodun 2014.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment