Smiley face

Fayose gbe awon ode ibile dide lati koju awon Fulani darandaran

Leyin ikolu awon Fulani darandaran nipinle Ekiti, Gomina Fayose ti gbe awon ode ibile dide pelu atileyin to nipon lati koju awon Fulani darandaran. Awon kan ni igbese Fayose le da wahala nla sile laipe.

Kini ero ti yin?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment