Smiley face

E wa wo ohun ti omo Wasiu Ayinde mubo lati Canada

Okan ninu awon omo King Wasiu Ayinde ti oruko re n je Mustapha Adetunji lo ti ilu Canada de. Dide ti omokunrin naa de, ebun pataki meji lo gbele baba re lowo: iwe eri igbelu Canada ati iwe eri to gba gboye nile eko York University ti Toronto.

Ohun ti bobo naa te jade lori ero instagram re ni yii:

"Upon touch down I went to greet my dad with my citizenship and degree from University @kingwasiuayindemarshal is the proud dad. Thanks for everything dad. Am greatful. #lokeloke #sheynaplayplay"
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

1 comments:

  1. Se omo Wasiu wa legbe won ninu foto yi? Omo jo agbalagba gan!

    ReplyDelete