Smiley face

Won fi ami-eye da Alaafin Oyo ati Ooni Ile Ife lola


Awon egbe Progressive Association In Christ (Egbe Olanrewaju) ti Methodist Church Nigeria Diocese tiluu Oyo, Oyo Circuit Methodist Cathedral, fi ami eye Extra Ordinary Ambassador of Peace da Alaafin Oyo, Oba Lamidi Adeyemi ati Ooni ti ile Ife, Oba Enitan Adeyeye Ogunwusi lola. Eleyii ni won se fun awon oba alaye mejeeji yii fun akitiyan won lati je ki ife gbooro lawujo awon omo Oduduwa.



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment