Smiley face

Iwosan ibile: Ogun iko

Awon eroja ta ma lo niwonyi:

  1. Orogbo bi 20 si 25
  2. Ataale ekun owo meta
  3. Aayu ekun owo meta
  4. Igo oyin kan

Bi a se ma pese won ni yii:

Gbogbo eroja ti a daruko loke yii: orogbo, aayu ati ataale ni a ma lo papo. Leyin eyi ni a ma da sinu igo oyin.

Lilo:
E ma mu sibi kan leemeta lojumo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment