Smiley face

Won ti gbade fun Arsenal: Asisat Oshoala fo fayo

Asisat Oshoala
Egbe agbaboolu Arsenal ti awon obirin ti gbegba oroke ninu idije FA CUP ti orileede Biritiko bayii. Aseyori yii lo waye nigba ti Arsenal feyin Chelsea janle pelu ami ayo ookan si oodo (1-0). 

Omo Naijiria ti n gba boolu fun Arsenal, Asisat Oshoala, lo fi aworan yii sita lati fi safinhan bi inu re ti dun to pelu aseyori tuntun naa. Igba kerinla ni yii ti egbe Arsenal ti awon obirin yoo ma gba ife-eye FA CUP ti ilu England.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment