Smiley face

Agbara ti kun oju titi Gomina Ambode


Iroyin kan to sare wole lo n salaye wi pe, titi tuntun ti Gomina Ambode sese si, ti kun fun ọpọlọpọ agbara bayii eleyii to je ko nira fun awon ọkọ lati koja. 

O ni lati je wi pe awon agbasẹ se ona naa ni ko sise alubarika sibẹ. Bawo ni won yoo se se ona ti ko ni gbẹ kọta ti omi yoo ma gba kọja si i?

Walahi! maa so fun Ogbeni Ayonride to je komisanna fun etigbọ ti ipinle Eko. 

Wo n gbodo wa nnkan se si ni kiakia.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment