Smiley face

Ayajo oni ni Sani Abacha ku lodun 1998

Oni ni i sami ayajọ ti Sani Abacha jade laye, 08-06-1998; nnkna bi odun mejidinlogun (18) seyin. 

Bi o tilẹ jẹ wi pe, atejade lati ile ise ijoba sọ wi pe, ikolu ọkan lo seku pa maanu naa. Sugbon awuyewuye kan pada jade wi pe, ọkan ninu awon ọmọge onidodo ilu India ti Abacha ma n fi "dodo" won panu lo fun ni Apple iku jẹ. 


Eleyii ti won lo lowo awon ọta Abacha ninu. Titi di akoko yii, enikeni ko tako awuyewuye naa wi pe, irọ ni.

Bi eniyan se rere laye, aye o ni gbagbe rẹ. Bi eniyan si se buburu inu itan naa ni yoo wa.

Kini ni eyin fẹ kaye fi ranti yin nigba tẹ ẹ ba lọ tan?

Lonii, 08-06-2016, Stephen Keshi naa ti dara ilẹ. Okunrin to lo gbogbo ẹbun ati agbara rẹ fun idagbasoke ati okiki Naijiria ko to jade laye.

Iroyin to kan wa bayii si sọ wi pe, won ti gbe oku okunrin naa lọ sile igboku kan to wa ni Benin.

Ki Oluwa dẹlẹ fẹni to lọ. Amin

MKO Abiola, General Sani Abacha, Sir Michael Otedola ati Major-General Abdulkareem Adisa
IBB ati Abacha

Abach ati iyawo re, Maryam
Awon agba awo
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment